Ékísódù 23:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin yóò sí máa sìn Olúwa Ọlọ́run yin, òun yóò si bù sí oúnjẹ rẹ. Èmi yóò mú àìsàn kúrò láàrin rẹ.

Ékísódù 23

Ékísódù 23:18-33