Ékísódù 23:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mú èso àkọ́so ilẹ̀ rẹ tí ó dára jùlọ wá sí ilé Olúwa Ọlọ́run rẹ.“Ìwọ kò gbọdọ̀ fi omi ọmú ìyá ewúrẹ́ bọ ọmọ ewúrẹ́.

Ékísódù 23

Ékísódù 23:9-24