Ékísódù 23:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ìgbà mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni àwọn ọkùnrin yín yóò máa wá fi ara hàn ní iwájú Olúwa Ọlọ́run.

Ékísódù 23

Ékísódù 23:10-25