Ékísódù 23:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ máa sọ́ra, kí ẹ sì ṣe ohun gbogbo tí mo wí fún un yín. Ẹ má se pe orúkọ òrìṣà, kí a má se gbọ́ orúkọ wọn ní ẹnu yín.

Ékísódù 23

Ékísódù 23:4-16