Ékísódù 23:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìwọ kò gbọdọ̀ tan ìròyìn èké kalẹ̀: Ìwọ kò gbọdọ̀ ran ènìyàn búburu lọ́wọ́ láti jẹ́rìí èké.

Ékísódù 23

Ékísódù 23:1-9