Ékísódù 22:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ọkùnrin kan bá fún aládùúgbò rẹ̀ ní fàdákà tàbí ohun èlò fún ìtọ́jú, ti wọ́n sì jí gbé lọ́dọ̀ aládùúgbò rẹ̀, tí a bá mú irú olè bẹ́ẹ̀, yóò san án padà ní ìlọ́po méjì.

Ékísódù 22

Ékísódù 22:1-16