Ékísódù 22:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ pẹ̀lú agbo màlúù rẹ àti agbo àgùntàn rẹ. Jẹ́ kí wọn wà lọ́dọ̀ ìyá wọn fún ọjọ́ méje, kí ìwọ kí ó sì fi wọ́n fún mi ní ọjọ kẹjọ.

Ékísódù 22

Ékísódù 22:21-31