Ékísódù 22:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbínú mi yóò ru sókè. Èmi yóò sì fi idà pa ọ. Ìyàwó rẹ yóò di opó, àwọn ọmọ rẹ yóò sì di aláìní baba.

Ékísódù 22

Ékísódù 22:20-25