Ékísódù 21:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí akọ màlúù bá kan ẹrúkùnrin tàbí ẹrúbìnrin pa, olówó rẹ̀ yóò san ọgbọ̀n sékélì fàdákà fún ẹni tó ni ẹrú, a ó sì sọ akọ màlúù náà ni okúta pa.

Ékísódù 21

Ékísódù 21:22-36