Ékísódù 21:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ọkùnrin kan bá lu ẹrúkùnrin tàbí ẹrúbìnrin rẹ̀ ní ojú, ti ojú náà sì fọ́, ó ni láti jẹ́ kí ẹrú náà lọ ní òmìnira fún ìtanràn ojú rẹ̀ ti ó fọ́.

Ékísódù 21

Ékísódù 21:17-31