Ékísódù 21:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ọkùnrin kan bá fi ọ̀pá lu ẹrúkùnrin tàbí ẹrubìnrin rẹ̀, ti ẹrú náà sì kú lójú ẹṣẹ̀, a ó fi ìyà jẹẹ́.

Ékísódù 21

Ékísódù 21:15-28