Ékísódù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó sí i, ó sì rí ọmọ náà. Ọmọ náà ń sunkún, àánú ọmọ náà sì ṣe é. Ó wí pé “Ọ̀kan nínú àwọn ọmọ Hébérù ni èyí.”

Ékísódù 2

Ékísódù 2:3-15