Gbogbo àwọn ènìyàn náà sì pa ohùn wọn pọ̀ wọ́n sì dáhùn wí pé, “Àwa yóò se ohun gbogbo ti Olúwa wí.” Mósè sì mú ìdáhùn wọn padà tọ Olúwa lọ.