Ékísódù 19:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sọ̀kalẹ̀ sí orí òkè Ṣínáì, o sì pe Mósè wá sí orí òkè náà. Mósè sì gun orí òkè.

Ékísódù 19

Ékísódù 19:10-24