Ékísódù 19:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì kó àwọn ènìyàn tí ó jáde láti ibùdó wá pàdé Ọlọ́run, wọ́n dúró nítòsí òkè.

Ékísódù 19

Ékísódù 19:14-22