Ékísódù 19:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí wọn kí ó sì múra di ọjọ́ kẹ́ta, nítorí ni ọjọ́ náà ni Olúwa yóò sọ̀kalẹ̀ sí orí òkè Ṣínáì ni ojú gbogbo àwọn ènìyàn.

Ékísódù 19

Ékísódù 19:2-14