Ékísódù 18:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́tírò, àna Mósè, òun àti aya àti àwọn ọmọ Mósè tọ̀ ọ́ wá nínú ihà tí ó tẹ̀dó sí, nítòsí òkè Ọlọ́run.

Ékísódù 18

Ékísódù 18:1-6