Ékísódù 18:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ méjèèjì. Orúkọ Àkọ́bí ń jẹ́ Gésómù (àjòjì); nítorí Mósè wí pé, “Èmi ń se àlejò ni ilẹ̀ àjòjì.”

Ékísódù 18

Ékísódù 18:1-8