Ékísódù 17:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì dá Mósè lóhùn pé, “Má a lọ ṣíwájú àwọn ènìyàn, mú nínú àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì pẹ̀lú rẹ, mú ọ̀pá tí ìwọ fi lu odò Náìlì lọ́wọ́ kí ó sì máa lọ.

Ékísódù 17

Ékísódù 17:1-13