Ékísódù 17:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósúà se bí Mósè ti wí fún un, ó sì bá àwọn ará Ámélékì jagun; nígbà tí Mósè, Árónì àti Húrì lọ sí orí òkè náà.

Ékísódù 17

Ékísódù 17:4-12