Ékísódù 16:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òwúrọ̀, ẹ̀yin yóò ri ògo Olúwa, nítorí òun ti gbọ́ kíkùn tí ẹ kùn sí i. Ta ni àwa ti ẹ̀yin yóò máa kùn sí wa?”

Ékísódù 16

Ékísódù 16:1-8