Ékísódù 16:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ará Ísírẹ́lì jẹ mánà fún ogójì ọdún títí wọ́n fi dé ilẹ̀ Kénánì ni ibi ti èso ti wà fún wọn láti jẹ; Wọ́n jẹ mánà títí tí wọ́n fi dé ilẹ̀ agbégbé Kénánì.

Ékísódù 16

Ékísódù 16:28-36