Ékísódù 16:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Mósè wí pé, “Èyí ni ohun tí Olúwa pàṣẹ: ‘Ẹ mú òṣùnwọ̀n ómérì mánà kí ẹ sì pa á mọ́ de àwọn ìran ti ń bọ̀, kí wọn kí ó lè rí oúnjẹ ti èmi fi fún un yín jẹ ní ijù, nígbà tí mo mú un yín jáde ni ilẹ̀ Éjíbítì.’ ”