Ékísódù 16:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wí fún wọn pé, “Àwa ìbá ti ọwọ́ Olúwa kú ni Éjíbítì! Níbi tí àwa ti jókòó ti ìkòkò ẹran ti a sì ń jẹ ohun gbogbo tí a fẹ́ ni àjẹyó, ṣùgbọ́n ẹ̀yin mú wa wá sí inú ijù yìí láti fi ebi pa wá tí a ó fi kú.”