Ékísódù 16:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíbẹ̀ṣíbẹ̀ àwọn ènìyàn kan jáde lọ ní ọjọ́ keje láti kó o, ṣùgbọ́n wọn kò ri nǹkan kan kó.

Ékísódù 16

Ékísódù 16:25-30