Ékísódù 16:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àṣálẹ́ ọjọ́ náà ni àwọn àparò fò dé, wọ́n sì bo àgọ́ mọ́lẹ̀, ní òwúrọ̀ ìrì sì sẹ̀ yí gbogbo àgọ́ náà ká.

Ékísódù 16

Ékísódù 16:12-14