Ékísódù 15:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú agbára ńlá rẹ ti ó tóbiìwọ bi àwọn ti ó dìde sí ọ ṣubú.Ìwọ rán ìbínú gbígbóná rẹ;Tí ó run wọ́n bí ìgémọ́lẹ̀ ìdí koríko

Ékísódù 15

Ékísódù 15:1-8