Ékísódù 15:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kẹ̀kẹ́-ogun Fáráò àti ogun rẹ̀ni ó mú wọ inú òkun.Àwọn ọmọ ogun Fáráò tó jáfáfá jùlọni ó rì sínú òkun pupa.

Ékísódù 15

Ékísódù 15:2-6