Ékísódù 15:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Míríámà kọrin sí wọn báyìí pé:“Ẹ kọrin sí OlúwaNítorí òun ni ológo jùlọẸṣin àti ẹni tí ó gùn únNi òun bi subú sínú òkun.”

Ékísódù 15

Ékísódù 15:14-26