Ékísódù 14:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó mú ẹgbẹ̀ta (600) ọmọ ogun oníkẹ̀kẹ́ tí ó jáfáfá jùlọ àti gbogbo ọmọ ogun oníkẹ̀kẹ́ mìíràn ní Éjíbítì, olórí sì wà fún olúkúlùkù wọn.

Ékísódù 14

Ékísódù 14:6-12