Ékísódù 14:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò yóò ronu pé àwọn ọmọ Isírẹ́lì ń ráre káàkiri ní ìdààmú ni àti wí pé ihà náà ti sé wọn mọ́.

Ékísódù 14

Ékísódù 14:1-13