Ékísódù 14:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì na ọwọ́ rẹ̀ sí orí òkun, òkun sì padà bọ́ sí ipò rẹ̀ nígbà ti ìlẹ̀ mọ́. Àwọn ará Éjíbítì ń sá fún omi òkun, Olúwa sì gbá wọn sínú òkun.

Ékísódù 14

Ékísódù 14:25-31