Ékísódù 13:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ọjọ́ méje ni ìwọ yóò fi jẹ àkàrà tí kò ní ìwúkàrà nínú àti pé ní ọjọ́ keje ni àjọ yóò wà fún Olúwa.

Ékísódù 13

Ékísódù 13:1-12