Ékísódù 13:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìkùùku náà kò kúrò ní ààyè rẹ̀ ní ọ̀sán, bẹ́ẹ̀ ni, òpó iná kò kúrò ní ààyè rẹ̀ ni òru, ní iwájú àwọn ènìyàn náà.

Ékísódù 13

Ékísódù 13:17-22