Ékísódù 13:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì mú ọ̀nà wọn pọ̀n láti Súkótì lọ, wọ́n sì pàgọ́ sí Ẹ́tamù ní etí ihà.

Ékísódù 13

Ékísódù 13:14-22