Ékísódù 13:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà Ọlọ́run darí àwọn ènìyàn rọkọ gba ọ̀nà ihà ní apá okùn pupa. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jáde kúrò ní ilẹ̀ Éjíbítì pẹ̀lú ìmúra fún ogun.

Ékísódù 13

Ékísódù 13:10-21