Ékísódù 12:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹran tí ìwọ yóò mú gbọdọ̀ jẹ́ akọ ọlọ́dùn kan tí kò lábùkù, ìwọ lè mú lára àgbò tàbí ewúrẹ́.

Ékísódù 12

Ékísódù 12:2-12