Ékísódù 12:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa ti mú kí àwọn ènìyàn yìí rí ojú rere àwọn ará Éjíbítì wọ́n sì fún wọn ní ohun tí wọ́n béèrè fún, wọ́n sì ko ẹrù àwọn ará Éjíbítì.

Ékísódù 12

Ékísódù 12:28-37