Ékísódù 12:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò àti àwọn ìjòyè rẹ̀ àti gbogbo àwọn ara Éjíbítì dìde ní ọ̀gànjọ́ òru, igbe ẹkún ńlá sì gba gbogbo ilẹ̀ Éjíbítì, nítorí kò sí ilé kan tí ó yọ sílẹ̀ tí ènìyàn kan kò ti kú.

Ékísódù 12

Ékísódù 12:26-31