Ékísódù 11:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Igbe ẹkún ńlá yóò sọ jákèjádò gbogbo ilẹ̀ Éjíbítì. Irú ohun búburú tí kò sẹlẹ̀ rí tí kò sí tún ni sẹlẹ̀ mọ́.

Ékísódù 11

Ékísódù 11:5-9