Ékísódù 10:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè dáhùn ó wí pé, “A ó lọ pẹ̀lú àwọn ọmọdé àti àgbà wa, pẹ̀lú àwọn ọmọ wa ọkùnrin àti ọmọ wa obìnrin pẹ̀lú agbo àgùntàn wa àti agbo màlúù wa nítorí pé a gbọdọ̀ ṣe ajọ fún Olúwa.”

Ékísódù 10

Ékísódù 10:4-19