Ékísódù 10:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Mósè àti Árónì tọ Fáráò lọ, ti wọn sí wí fún pé, “Èyí ni Olúwa, Ọlọ́run àwọn Hébérù sọ: ‘Yóò ti pẹ́ to ti ìwọ yóò kọ̀ láti tẹrí ara rẹ ba ní iwájú mi?

Ékísódù 10

Ékísódù 10:1-5