Ékísódù 10:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò sì ránṣẹ́ pe Mósè ó sì wí fún un pé, “Lọ sìn Olúwa, kódà àwọn obìnrin àti àwọn ọmọdé lè lọ pẹ̀lú yín, ṣùgbọ́n kí ìwọ kí ó fi agbo àgùntàn àti agbo màlúù yín sílẹ̀.”

Ékísódù 10

Ékísódù 10:16-29