Éfésù 4:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òye àwọn ẹni tí ó ṣókùnkùn, àwọn tí ó sì di àjèjì sí ìwà-bí-Ọlọ́run nítorí àìmọ̀ tí ń bẹ nínú wọn, nítorí lílè ọkàn wọn.

Éfésù 4

Éfésù 4:16-25