Éfésù 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí àwa má ṣe jẹ́ èwe mọ́, tí a ń fi gbogbo afẹ́fẹ́ ẹ̀kọ́ tì síwá tì sẹ́yìn, tí a sì fi ń gbá kiri, nípa ìtànjẹ ènìyàn, nípa àrékérekè fun ọgbọ́nkọ́gbọ́n àti mú ni sìnà;

Éfésù 4

Éfésù 4:8-17