Éfésù 3:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí Kírísítì lè máa gbé inú ọkàn yín nípa ìgbàgbọ́; pé bí ẹ ti ń fi gbòǹgbò múlẹ̀ tí ẹ sì ń fi ẹsẹ̀ múlẹ̀ nínú ìfẹ́;

Éfésù 3

Éfésù 3:15-20