Éfésù 3:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ẹni tí àwa ní ìgboyà, àti ọ̀nà pẹ̀lú ìgbẹ́kẹ̀lé nípa ìgbàgbọ́ wa nínú rẹ̀.

Éfésù 3

Éfésù 3:9-14