Éfésù 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí oun ni àlàáfíà wa, ẹni tí o ti ṣe méjèèjì ni ọ̀kan, tí ó sì ti wó ògiri ìkélé ti ìkórira èyí tí ń bẹ láàrin yín.

Éfésù 2

Éfésù 2:12-22