Éfésù 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti ẹ̀yin, ẹ̀yin ni ó sì ti sọ di ààyè, nígbà ti ẹ̀yin ti kú nítorí ìrékọjá àti àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín,

Éfésù 2

Éfésù 2:1-9