Éfésù 1:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbé e ga ju gbogbo ìsàkóso, àti àṣẹ, àti agbára, àti ilẹ̀ ọba àti gbogbo àpèlé orúkọ tí a lè ti fún mi, kì í ṣe ni ayé yìí nìkan, ṣùgbọ́n ni èyí tí ń bọ̀ pẹ̀lú.

Éfésù 1

Éfésù 1:13-23